111 most dreams and intrepretations by dauda awwal

Page 1

111 MOST DREAMS AND INTERPRETATIONS (Dictionary of Dreams)

YORUBA & ENGLISH WRITTEN BY

DAUDA AWWAL

1


111 MOST DEARMS AND INTERPRETATIONS BY DAUDA AWWAL CopyrightŠ Dauda Awwal January 2018 All rights reserved, no part of this book may be reproduced, stored in retrieval system, or transmitted to any form or by any means electronics or mechanical including photocopying without in written from the author. For Permission, please contact Awwal Production International 104 Reston Crescent Eltham, London SE9 2JH, United Kingdom Telephone:0044 7466 767 942 Email: dawwal@yahoo.com.

2


CONTENTS Contents…………………………………………………………………………….3 Dedication………………………………………………………………………….4 Introduction……………………………………………………………………5-6 111 Dreams and Interpretations……………………………………7-38

3


Dedication I dedicate this book to my son-Shamsuddeen Okanlawon Awwal

4


INTRODUCTION How much do we know about our dreams? do they affect our daily activities? Is it true dreams are seen as a message or method of communication between God and Man? Is it true Joseph had dream: saw eleven stars and Sun and Moon prostrating to him? then what happened to him and his brother? All the answer is in this book. Classical collection of dream interpretations is in this book. You will find the meaning of your most daily dreams in this book. Dreams have always been held to have the greatest significance. Dream is seen as a method of communication, message from God in any form. Some Philosopher says dreams attached to certain thought of the dreamer, but the picture provided in the dream gives the clearest message to the dreamers: for example, when Prophet Joseph said to his father ’O my father! I saw eleven stars and the sun and the moon, I saw them prostrating to me. His father Jacob warned him not relate his dream to his brothers, least they devise against him. Joseph’s Dream comes true. He became King of Egypt and his brothers fell down in prostrating before him to demonstrate their respect and honour to him. He said to his father ‘’My father this is the fulfilment of my dream years back, my Lord has made it come true’’. Sometimes the dreams are straightforward in their meaning to the dreamer like the one I mentioned regarding Joseph. Almighty God communicates with us in many ways through the vision, dreams and sign, it is left for the dreamer to learn and recognize the voice of God through his/her dreams. 5


Dreams come for instructions, warning, directions, teaching, messages. Dreams don’t always tell a simple story, and sometimes the field of dream research becomes more fascinating when people from different cultures and backgrounds report having similar dreams. There are meaning for symbols and images in dreams. Some dreamers have: Precognitive Dreams: These are psychic dreams that can foretell the future. Some have Warning Dreams: These dreams alert them to possible danger or problems ahead. Therefore, I brought to you in this book 111 Dreams and the meaning. Here are the most common 111 dream symbols, and their meanings inYoruba and English. I hope this book will be useful at all levels. DAUDA AWWAL 13/01/2018

6


111 MOST DREAMS AND INTERPRETATIONS BY DAUDA AWWAL 1-Bi enia bala ala pe oun ri Oorun ti o tan imole tabi Osupa onimole ni opolopo igba, eni na yio je olokiki laiye ti emi re ba gun. Bi o ba ri Oorun ti o wokun tabi osupa ti o wokun, ibanuje ati aisan ni itumo re. 1-Sun: The sun signifies fame, unity, abundance and wealth. Sun set and darkness of the moon signifies opposite. 2-Ti enia ba nri okunkun lopolopo igba, awon aburu fe sele si onitoun tabi ara ile re. Ki o kun fun adua. 2-DARKNESS: Darkness signify unfavourable omen, to get out of darkness denotes good news to the dreamer. 3-Ti enia ba nta eja tutu tabi o gbe eja loju orun lopolopo igba, eni na yio ni owo tabua ki o to fi aiye sile. 3-FISH: Fish signify good health and fortune but dead fish denotes bad omen. 4-Bi malu ba nle enia kiri loju orun tabi malu na kan an, awon ota idile iya tabi baba tabi awon ore nlepa emi eni na lati pa a. Ki eni na mura si oro ara re. 4-COW: Cow indicates good luck and many cows denotes good fortune. 5-Eje riri loju orun fun aboyun kiise ala gidi, Ki o gbadua gidi lori oyun inu re. 5-BLOOD: Blood signifies bad omen bleeding denotes loss of property, vomiting blood is good for a poor person. 6-Riri awon olopa loju orun tumo si owo. 6-POLICE: To dream of police means money but being in the custody of a policeman signifies that you expect to be unjustly blamed by one who wishes you ill and the accusation will do you more favour.

7


7-Ki iyawo tabi oko ju oruka igbeyawo nu loju orun, kii se ala to dara. Ki won sora ki igbeyawo na ma daru. 7-RING: If a dreamer dreams saw a ring falls off his finger indicates evil and prison and death of a close friend or relative. To a pregnant woman, it denotes that her child will encounter many difficulties. To unmarried girl or woman, it’s a warning to beware of her present lover who will abandon her. To dream of having rings on your finger shows success in love. If engagement ring is taken off, it denotes bad omen. It is a bad sign for a young girl or woman who is engaged to be married to dream that she is wearing a wedding ring. To receive a ring as a present foretells unexpected news. 8-Ki enia ma ba ara re ni ile itoju awon oku kiise ala to dara,iku ojiji tabi aisan ni itumo re. 8-MORTUARY: Signifies sudden death. 9-Ki enia ma ri ero isoro-makirofonu ni opolopo igba loju orun tumo si ise oluwa. 9-MICROPHONE: Invitation to evangelism. 10-Elede loju orun tumo si ikilo, ki eni na jinna si awon iwa ese ki o ma ba kabamo. 10-PIG: To dream of a pig denotes warning against sins. 11-Ki enia ja si inu koto loju orun tumo si aisan nla. 11-PIT: If you dream you fell in to pit denotes sudden illness. 12-Ija loju orun tumo si asasi lati owo awon ota, ki eni na kun fun adua iso. 12-FIGHTING: Fighting foretells opposition to your wishes, if a sailor was fighting in his dream, it denotes storms and shipwreck.

8


13-Riri ogun loju orun tabi wiwa ni ile itaja-oogun lati fe gba alaye nipa ogun tumo si erenje tabi idunnu,ki enia lo ogun loju orun tumo si ipadanu owo,isegun ni itumo re ti ogun na ba koro. 13-MEDICINE: To dream you prescribe medicines denotes profit and happiness. To take it foretells loss of money and also means victory if the medicine is bitter. 14-Bi o ba la ala pe won ta oun ni ibon l’oju orun,kiise ala to dara.Awon ota nlepa emi re. 14-GUN: Gun foretells problem ahead to the dreamer, if you are handling it, is a bad omen if you are firing a gun denotes lawsuit. 15-Ikudu loju orun tumo si akanti/aseti.Ododo ife laarin oko ati iyawo,ti eja ba wa ninu ikudu na,iyawo eniti o la ala na ma bi ibeji.Ti opo ba ala na,yio ri okunrin rere miran fe. 15-POND: If a dreamer see a small pond denotes enjoyment of a beautiful woman’s love or an handsome man. if there are many fish,the woman will have twins .To a widow,she will remarry happily. 16-Bi enia da yepe si ara re tabi si ara eni mimo re tumo si abuku. Ki eni na sora nipa oro siso tabi ki o ma lo sibi ayeye ni asiko na. 16-SAND: If a dreamer dreams of having sand on his or her body or well-known person to him denotes disgrace, he should caution himself to talk. 17-Fifo bi eiye loju orun tumo si isegun ota tabi agbega lenu ise tabi agbega ninu ise Oluwa. 17-FLYING: Flying like a bird in dream denotes victory over enemies and promotion in the spiritual world. 18-Pipo eje loju orun tumo si aisan tabi jije majele loju aiye. Ki eni na sora fun apeje. 18-VOMITING BLOOD: Vomiting blood denotes sickness, caution what to eat. 9


19-Ifitipa bani lopo loju orun kiise ala to dara. Ki eni na sora fun ayanfe odale, ki o si kun fun adua lori adawole re. 19-RAPE: Beware of fake lover.He/She should pray hard. 20-Igun afara koja tumo si isegun lori awon isoro, ki eni na kun fun adua. 20-CROSSING THE BRIDGE: Crossing over the bridge is a victory over your enemies. Please, pray hard. 21—Riri ejo loju orun kiise ala to dara. Bi eni na ba ni oko tabi iyawo tabi afesona, ki o sora ki edeoyede-nla ma sele eyiti o le tu won ka.Bi o ba pa ejo loju ala tumo si isegun ota. 21-SNAKE: To dream you see a snake denotes imprisonment, sickness, hatred, disappointment and danger. To kill serpent or any snake in your dream is a victory over enemies. 22-Ki won ma aba aboyun lopo loju orun lai mo eni na lewu. Ti o ba je eni mo,ki a kun fun adua. 22-SEX WITH PREGNANT WOMAN: It is a bad omen for a pregnant woman to have sex in her dream or having sex with a pregnant woman is bad omen. 23-Ki enia maa ri ara re tabi elomiran ni ihoho loju orun tumo iberu, sise onje loju orun tabi tita epa, ati riri igba tabi koko ibile tumo si aisan, airije, airimu ati airina,sugbon idunnu ni itumo re bi o ba ri arewa obinrin loju orun. 23-NAKEDNESS: To see yourself naked or another in your dream signify fear, cooking, selling nut, holding calabash or traditional pot denotes sickness and poverty. To see a naked fair and beautiful woman signifies happiness. 24-Ki ile wo loju orun mo enia mole tabi o wo lu eni mimo loju orun tumo si ifaseyin.

10


24-DEMOLISHED BUILDING: To dream of demolished building foretells setback. 25-Ijamba oko loju orun tabi eje tumo si ajalu nla. 25-MOTOR ACCIDENT: Motor accident denotes disaster. 26-Ijamba-ina loju orun tumo si wahala lenu ise tabi lori adawole, ki eni na kun fun adua. 26-FIRE: Fire disaster signify trouble, pray hard. 27-Poosi loju orun tumo iku ojiji ore tabi ebi, ki eni na kun fun adua iso. Bi asiko ti eni na la ala na ba bosi asiko ti o fe lo si ibi ayeye igbeyawo.Bi oko tabi iyawo ti won fe se igbeyawoo ba la ala na,enikan ninu won yio se aisan lehin igbeyawo won. 27-COFFIN: Expect bad news when you see a coffin, if you are about to wed you will sick for the first year after wedding if you are about to attend wedding groom or bride will sick after the wedding. Coffin also denotes sudden death of a friend or relative. 28- Olongbo dudu, aja dudu, eiye dudu tabi malu dudu tumo si ajalu lati owo awon aje. Ki eni na kun fun ajo iso ati eyonu aiye. 28-CAT: Black Cat, black Dog, black bird or black Cow denotes disaster from witches. Please, pray hard. 29-Iworan ni Sinima tabi iworan ninu ero amohunmu-aworan tabi laptop loju orun tumo si abuku ati asasi lati owo ota.Ki eni na kun fun adua. 29-CINEMA: Watch a film at cinema or on television or laptop or computer in your dream denotes shameful. Pray hard. 30-Riri agadagodo nla tabi kekere lojuorun tumo si akoba, ki eni na kun fun adua ki won ma fi sinu tubu. Ti o ba ri ara re ninu tubu loju orun tumo idilowo awon ota lori adawole re.

11


30-PADLOCK: Whoever dream of padlock will probably never be in real financial trouble. He should be careful of friends who can put him in trouble of imprisonment. 31-Aseyori ni eyin riri loju orun. Ti egg ba sonu ki o so ahan re,bi o ba fo eyin, ibanuje gidi ni itumo re. 31-EGG: Eggs foretells success but if you loss eggs, keep guard on your tongue, if you break eggs it foretells sadness. 32-Ibanuje tabi Aisan ni riri iboji loju orun. Ti olowo ba la ala pe won bo oun mo inu saare, ki o kun fun adua ki o ma ku ni talaka,ti talaka ba nla ala pe won bo oun mo’nu saare,yio ni owo ki o to ku.Ti enia bari saare ki o sora fun aisan tabi ijanikule. 32-GRAVE: If they put you in a grave and buried, that indicates that you will die poor if you a rich person, pray hard, if you are a poor you will get plenty money.to see grave denotes disappointment and sickness. 33- Ile iwosan tumo si aisan 33-HOSPITAL: Hospital signifies illness, 34-Wiwo aso dudu tabi riri aso dudu loju orun tumo ibanuje nla laarin ebi. 34-BLACK CLOTHES: Black clothes foretells sorrow within the family. 35-Agbado riri loju orun/tabi orisirisi eso tabi gbigbe koto ti omi sun jade ninu re tumo si agbega ati aseyori. 35-MAIZE/FRUITS: Maize or pit filed with water or variety of fruits denotes success 36-Ki enia ma ri ara re lori oke nla tabi ninu osupa tumo si asiwaju/agbega. 36-ROCK: To dream of rocks denote promotion. 37-Gigun esin loju orun tumo aseyori, agbega, erenje ati ibori ota. 12


37-RIDING HORSE: Riding a horse foretells success and victory over enemies. 38-Malu ti o tinrin-iyan, airije sugbon malu sisanra tumo orire ati ola. 38-COW: Lean cow denotes disaster but fat cows signifies good luck and fortunes. 39-Onje jije loju orun kiise ohun ti o dara. 39-FOOD: Eating food in your dream is a bad omen. 40-Ki bata obinrin ti o ni oko tabi okunrin ti o ni iyawo sonu loju orun tumo si ajatuka laarin oko ati iyawo tabi afesona. 40-SHOES: A Married Woman to loss her shoes or Married Man to loss his shoes denote separation. The same meaning to the fiancÊes. 41-Ki Iborun obinrin sonu tabi aso ibora okunrin sonu loju orun tumo aibale okan ninu igbeyawo tabi afesona. 41-VEIL: A married woman to loss her veil or duvet signifies unpeaceful marriage. 42-Alantakun loju orun tumo si isora fun iyawo/afesona tabi ore odale. 42-SPIDER: Spider forewarns you to be careful of your fiancÊe or friend who is planning to betray you. 43-Akeke loju orun tumo si jamba ore. 43-SCORPION: Scorpion signifies disappointment from friends 44—Ki enia la ala pe enikan nbu oun, ala burburu ni: sugbon bi eniti o la ala na ba nbu enia loju orun aseyori ni itumo re. 44-ASSAULT: To be assault is a bed omen but good if you assault someone. 45- Ki enia ri odo tabi eniti nmu igbo tabi siga tabi eniti nfoso tumo si idunnu. 13


45-SEA: Sea or see someone smoking cigarettes or marijuana denotes joy. 46-Riri Ewa tabi jije ewa loju orun tumo si aisan tabi wahala. 46-BEANS: Beans or eating beans signifies trouble or sickness. 47-Tolotolo nse ikilo nipa aisan nla. 47-TURKEY: Turkey forewarns sickness. 48-Ki enia ma san owo fun oloja loju orun tumo si bibi omokunrin,bi owo ba junu lowo re,ayanfe re yio dale,Bi o ba he owo loju ala,wa se opolopo wahala ni asiko na. 48-MONEY: To dream that you are paying money foretells the birth of a son, if you lose money you will be deceived by your lover. If you pick up loose money signifies hard work. 49-Omi tomo tumo si oro idunnu. 49: CLEAN WATER: Clean water signifies good news. 50-Kiko leta loju orun tumo irohin idunnu 50-LETTER: Writing a letter foretells good tidings. 51-Ki enia ri Onirungbon ti o kun repete tumo owo, ti irungbon na ba kere, ki eni na sora fun oro ile-ejo. Bi Agbejoro tabi Onimimo tabi Ojogbon tabi Alfa-nla tabi Agba Pasto ba la ala ri Onirungbon kikun aseyori ni itumo re,sugbon bi omode ba la ala na wahala nla mbo fun u.Bi obinrin ti ko ni oko ba la ala pe oun ni’rugbon,oko re yio ku,ayafi ki o kun fun adua. 51: BEARD: To dream of someone has long rough beard signifies money, but trimmed beard denotes danger or law suits. If a lawyer or knowledgeable person or Scholar or pastor/imam see a beard man signifies success, good crops for farmer. Bad omen for a married woman to have beard in her dream, if denotes of loss of her husband.

14


Good luck for unmarried woman, if a girl see herself with beard she will marry soon. 52-Ki enia ri ile ifowopamo ala na nse ikilo idawole owo sise. 52-BANK: Bank foretells a warning against investment. 53-Ki enia ri Ikoerusi/bag tumo si aisan, bi o ba gbe bagi kolofo tumo si osi,bi o ba gbe eyiti owo die wa ninu re tumo si nini owo die. 53-BAG: To see a bag denotes sickness. Carrying an empty bag denotes poverty. Carrying a full bag signifies of having little money. 54-Orun sisun labe igi tumo si ajalu buruku. Bi enia basun labe igi ti oni opolopo ewe tumo si ifeyawo tabi loko.wahala ni ki enia ri ara re labe igi ti ko ni ewe. 54-SLEEPING UNDER THE TREE: Sleeping in your dream signifies disaster, but if you see yourself sleeping under blossoming trees is a sign of comfort, but it denotes danger under dry trees without leaves. 55-Ategun tumo igbadun sugbon ategun agan tumo si wahala, ogun aiye. 55-WIND: Wind signifies comfort but strong breeze denotes war of life. 56-Omu/Oyan.Bi o ba ri oyan re ti o rewa, ala daradara ni,sugbon abileko ba nri oyan re lopolopo igba, yio padanu oko re. 56-BREAST: A married woman to see her breast all the time in her dream she will lose her husband. It is a good sign for a man or unmarried woman. 57-Ki enia sora fun ijamba oko tabi iku ojiji bi enia ba ri oko ojurin/train loju ala. 57-TRAIN: To dream of train denotes sudden death or car accident.

15


58-Masalasi: Eniti o ri masalasi loju ala ti o si je musulumi, ki eni na ma fi esin re sile, idunnu mbo fun u. Sosi: Ti kirisiteni ba ri ara re ni ile isin, idunnu kan mbo fun u. 58-MOSQUE/CHURCH: To dream you are in church/mosque signifies happiness and good news 59-Bi o ba la ala pe won ta o ni ofa ti eje ko jade lara re, ore ojiji kan mbo wa fun o lati odo eniti o ta o lofa loju orun, sugbon bi o ba fi ara pa die, oore na si ma wa teo lowo. 59-SWORD: If you dream you have been stabbed with a sword, you will receive an extraordinary gift from the person who attacked you, if blood is too drawn, the advantage is less if you are morally wounded, you will receive several good gifts from him or someone else. 60-Ti enia ba ri karoti loju ala yio ri opolopo ere lori adawole re. 60-CARROT: Carrot denotes profit by inheritance. 61-Riri adan loju orun tumo ibanuje, ki eni na sora fun eletan. 61-BAT: Seeing bat in your dream is a bad omen, someone is deceiving you. 62-Wiwe loju orun tumo ibanuje ati aisan, sugbon wiwe lodo tumo si ibanuje ojo iwaju ti ombo, ki eni na kun fun adua sugbon bi ori eniti o nwe lodo ba yo sita,aseyori ni itumo re. 62-BATH: Bath in the bathroom denotes sorrow, swimming in the pool signifies sadness ahead. 63-Ki won ju enia ni okuta loju ala nse ikilo ki eni na so ahan re. 63-STONE: To dream of having a stone thrown at you denotes that you are in danger through of your speech. Be-careful of your tongue. 64-Bi olowo ba la ala pe oun banuje loju orun,o tumo si ifi arapa,ti olosi ba la a,yio ri iranlowo lati odo olowo.

16


64-INJURY: If a rich man is sad in his dream and receive an injury, signifies to beware of enemies. If a poor man injured he will get aid from a rich man. 65-Orin kiko loju orun tumo si ibanuje sugbon bi o ba gbo ohun orin kiko eyi tumo si Alaafia alamodi. 65-SONGS: If anyone dreams of singing, he will have a reason to weep. Hearing songs denotes of recovery of health. 66-Riri Aja loju orun ti ko ba gbo mo o, ala ti o dara ni,o tumo ife, sugbon bi o ba gbo ti o sibu o je,ota fe pa o ni.Ki o kun fun adua ki o si toju arare. 66-DOG: Dog denotes love, friendship if you are in love with someone but if a dog barks and tear your clothes signifies enemy is trying to deprive you of your livelihood. 67-Ki enia lala pe oun joba-de ade tumo si aisan. Ki eni na kun fun adua. 67-THRONE: To dream of becoming king or see empty throne signifies bad news. 68-Oruka: Bi aboyun ba lala ri oruka loju orun, omo inu re yio se wahala pupo ki o to di enia gidi lawujo, bi obinrin ti o ni afesona ba ri oruka loju orun ki o sora ki afesona re ma dale re. Bi oruka ba sonu lowo iyawo tabi oko, enikan ninu awon mejeji ma ku,ki won kun fun adua.Bi enia ba ri oruka lowo ara re,o tumo si iyi ati agbega,sugbon bi eni na ko ba ti loko tabi fe iyawo, o lewu.Eniti o nse ise ti o lodi si ofin ilu ti o wa:ti o ba la ala pe oruka sonu lowo oun, ewon ni itumo re. 68-RING: If a pregnant woman dreams of ring, her child will encounter difficulties in life, to a girl it is a warning to beware of her present lover. Misunderstanding between husband and wife if any one of them losing ring in their dream. To dream of having rings on your fingers signifies dignity.it is very dangerous for unmarried man or woman if taken off fingers. 17


69-Ile onje-:Ki enia ma jeun ni ile onje loju orun tumo si aisan. 69-RESTAURANT: Eating in a restaurant denotes sickness 70-Eni ti o nri Ehoro loju orun lopolopo igba, ki o mura si oro ile aiye re,bi beeko,ki yio je enia gidi ti yio fiku. 70: RABBIT: If anyone dreams of Rabbit, it is a strong warning against unknown enemies trying to disgrace the dreamer.He/she may die poorer.To eat rabbit is bad omen. If a married woman dreams of rabbit she will have many children. 71-Eniti o ba la ala pe oun ni edeoyede pelu enikeni tumo si irohin airotele. 71-QUARREL: To dream of quarrelling signifies unexpected news. 72-Ki eniti ma ko leta loju orun tumo si aseyori sugbon ki enia ma pin leta lati ojule si ojule ki eni na sora kuro nipa itenubole kiri ati ofofo ki aburu nla ma sele si eni na. 72-LETTER: Writing letter signifies success and good news, distributing letters forewarns against backbiting. 73-Bi enia ba ri irori ti eje wa lara re tumo si iku olori ebi eni won nibi ijamba oko, ti irori na bamo, idunnu ati aseyori ni itumo re. 73-PILLOW: Pillow with blood foretells of losing head of the family in an accident. If the pillow is clean signifies joy and success. 74-Elede tumo si ilara awon ore. sugbon ti enia ba nta elede loju orun tumo si aisan,ki eni na ma da wole owo lasiko na,bi beeko ofo ni. 74-PIG: To dream of pig signifies envies, trading of pigs denotes sickness and losing money in investment. 75-Ago loju orun tumo aisan ,ti ago na ko ba sise ki eni na ma da wole owo sise lasiko na ti ko ba fe padanu.Bi alamu ago na ba dun,aseyori ni itumo re.

18


75-CLOCK: To dream of a wall clock strike denotes marriage and success if the clock stopped or breaking signifies serious illness. 76-Edie Didin loju orun tumo aisan, ti eniti o la ala na ba je agbe, opolopo eso tabi ile edie re ninu oko ni yio s’ofo . 76-CHICKEN: To dream of roasted chicken is a bad omen. To the farmer is a bad crop and lose of poultry. 77-Bi enia ba ri Olongbo ki o sora fun awon olosa abele,bi eni na ba pa olongbo loju ala tabi o rinna pade olongbo, ki eni na sora ki o ma jale eyiti o le ran an lo si ewon,bi enia ba je olongbo loju ala,yio ri dukia re ti ole gbe,ti eni na ba ja loju orun pelu olongbo ti olongbo si se e lese, aisan nla ni itumo re.Ki eni na kun fun adua. 77-CAT: Cat signifies a cunning thief, if the dreamer killed a cat, he will commit stealing that can send him to prison, if the dreamer eats cat’s flesh, he will get his stolen property from thief. If he fights with a cat and the cat scratched him, it is a bad omen. 78-Bi Awo onje ba fo lowo enikeni loju orun, inkan nla ma sonu lowo re tabi ki okan ninu awon ebi se aisan. 78-DISH: To dream of breaking dish accidentally foretells of losing one of your property or relatives. 79-Riri Agbe tabi Dokita tabi Nosi tabi igo-oju loju orun tumo idunnu. 79-Seeing DOCTOR/NURSE/SUN SHADE in your dream signifies happiness. 80-Okiki ni gbigbo ohun ilu loju orun 80-DRUM: To hear the beat of a drum denotes fame. 81-Ki enia fun Eerin lonje loju orun tumo si ise lodo gbajumo ilu.Bi o ba nsise pelu pelu olola ni asiko na won yio gbe e ga. 81-ELEPHANT: If a dreamer gives an elephant drinks or food or anything unharmful, he /she shall work for powerful person. If he/she 19


is working with powerful person during the time he had the dream, she/he will be promoted or transfer to highest position. 82-Riri opolopo eja loju orun tumo alaafia ati opolopo owo.Bi eniti ko ni oko tabi iyawo ba nri eja lopolopo igba, eni na yio ri iyawo tabi oko gidi fe.Bi aboyun ba bi oku eja loju orun,yio bi omo inu re loku.Bi enia ba de ogere sinu odo lati mu awon eja,ajalu buruku ni itumo re. 82-FISH: If you dream of many fish, it is a sign of good health and fortune. If unmarried person dreams of eating fish, he/she will marry soon, married person will have many children, dead fish foretells disappointment and quarrels. To a pregnant woman who gives birth to a dead fish will have a stillborn child. To catch sea fish is a bad omen. 83-Ki enia pa opolo tabi mu opolo loju orun tumo si wahala tabi iku ojiji, bi eni na ba ni oko tabi iyawo,bi eniti ko loko tabi iyawo ba la ala na,ki o sora fun awon olofofo.Idunnu ni opolo fun agbalagba ti o ba ri opolo loju orun. 83-FROG: To dream of frog foretells a warning against gossipers,it signifies joy for an old man or woman. To kill or catch frog foretells sudden death of relatives or friends 84-Ki enia ri igi ti okun fun opolopo ewe tutu tumo si idunnu. 84-TREE: To dream of green tree foretells happiness. 85-Igbeyawo loju orun tumo si aisan tabi iku ojiji: bi okunrin ba fe aburewa obinrin,iku ojiji ni itumo re,ki o se opolopo adua,bi o ba je arewa obinrin,idunnu ni itumo re,bi eni ti o la ala na ba je oluranlowo nibi ayeye igbeyawo,iro idunnu mbo fun eni na. 85-WEDDING: If a man dreams he is married to an ugly woman, it is a sign of sudden death, if the woman is pretty, it signifies happiness, if a sick person had wedding, it is a bad omen, it foretells sickness for the married man or woman, sudden death for the dreamer to se himself as a helper at venue of the wedding. 20


86-Ki enia ma mu miliki loju orun tumo si idunnu ati aseyori ati opolopo omo, ki enia ma fi miliki sofo loju orun, ala buruku ni eyi.Ki enia ma ta miliki loju orun tumo ife laarin eniti o la ala ati olufe re. 85-MILK: Drinking milk is very good sign, of good news, large family and success. Spilling milk is a sign of disaster, selling milk is a sign of love affairs to the dreamer. 86-Ki enia ri oko ti o nsise daradara loju orun tumo aseyori ati agbega, sugbon ti oko na ko ba sise,kiise itumo ti o dara.wahala mbo, ki eni na fi adua jagun. 86-MOTOR CAR: Good motor car signifies success and promotion, abandon car foretells trouble, pray hard. 87-Alupupu: Mavfi oro iba-obinrin re lopo tabi iba-okunrin re lopo jafara. 87-MOTOR CYCLE: Do not careless in your sexual encounters. 88-Riri keke loju orun tumo si igbadun lehin opolopo wahala, ki o se opolopo adua ki o ma ba ri wahala.. 88-BICYCLE: Riding bicycle signifies working hard to get comfort, pray against trouble 89-Ki enia ri okunrin/obinrin ni ihoho tumo si wahala,sugbon ti eni na ba ri obinrin pupa ni ihoho,idunnu ni itumo re,bi obinrin na ba je dudu tabi aburewa tabi arugbo dudu idojuti ati ijakule ni itumo re.Bi oko ba nri iyawo re ni ihoho lopolopo igba,eletan ni iyawo re,sugbon bi iyawo ba nri oko re ni ihoho lopolopo igba,aseyori fun oko re ni o tumo si.Bi o ba ri ore re ni ihoho,ija yio sele laarin yin.Bi o ba ri ara re ni ihoho,sora fun airina tabi aisan fun olowo,bi o ba ri ara re ni ihoho ninu masalasi tabi church ala buruku ni. 89:NAKED MAN/WOMAN: To dream of naked man foretells fear but a naked beautiful skinned woman, fair, foretells happiness, but if the dreamer see a naked old and ugly woman, it is a sign of shame and disappointment, if a husband sees his wife all the time naked she is 21


deceiving him, if wife sees her husband naked all the time this is a good sign for his success, if you see your friend naked, it signifies argument between you and him/her.to see yourself naked all the time it is a sign of poverty or sickness for the rich person. To see a naked man or woman in the mosque or church is a bad omen. 90-Abere tabi epa loju orun tumo si aseyori. 90-NEEDLE/NUT: Needle/Nut signifies success. 91- Jije Alubosa loju orun tumo si idunnu ati ibanuje. Kun fun adua 91-ONION: Eating onion in your dream signifies joy and sorrow, pray hard. 92-Riri Osan tabi mimu u tumo si ibanuje, ki eni na kun fun adua. 92-ORANGE: Seeing orange or drinking orange fortells sorrow, you have to pray hard. 93-Ki enia ri beba lopolopo igba tumo si owo nini. 93-PAPER: Seeing paper all the time signifies riches. 94-Ki enia ma ge irun fun enia kan ti o je ojulumo,eniti won ke irun fun na yio se aseyori lori nkan ti o da wole lasiko na,sugbon ki won ma ke irun tabi diri fun eniti o la ala,kiise itumo ti o dara fun eni naajakule nitumo re. 94: HAIR: To dream of cutting hair for a well-known person to you is a success to him/her: bad luck to the dreamer: It is a sign of disappointment. 95-Aguntan:Ki enia ni opolopo aguntan loju orun tumo si ini opolopo dukia/owo 95-SHEEP: To dream of having sheep denotes wealth 96- Ki enia so kokoro nu loju orun tumo si ileni kuro lenu ise tabi ki eni na padanu owo. 96-KEY: Losing key signifies of losing job or money. 22


97-Ija ina loju orun tumo ofo. 97-FIRE: Fire signifies disaster. 98-Eiyele/Ataba tumo idunnu ati alaafia 98-PIGEON/DOVE: Pigeon or Dove signifies happiness and health. 99-Ki enia gba oyin tabi fun enia loyin loju orun tumo si aseyori. 99-HONEY: To dream of receiving honey or giving signifies success. 100-Ki enia ri opolopo oke ti o yii ka tumo si isegun ota. 100-ROCKS: To dream of rocks surrounded you is a sign of victory over enemies. 101-Ki enia ri igbale loju orun tumo si iso ebi po.Enikan fe lo anfani re fun ara re ni ona ti ko dara lenu ise. 101-BROOM: Seeing a broom is a sign of associate family/someone is seeking to take advantage of you or your position at work. 102-Bi enia ba ri ferese iwaju ile ti o gbina,eniti o la ala na ma padanu egbon tabi aburo re okunrin,sugbon ti awon arakunrin re na ba wa ninu ala na, ti won si wa lehinkunle ile na,awon aburo/egbon re lobinrin tabi ebi kan ni yi o ku lojiji.Bi enia ba nyoju sita lati oju ferese,eni na yio se irinajo losi ilu okere,yio si se orire ki o to pada si ilu baba re. 102-WINDOW: To dream of windows at the front of the house destroyed by fire denotes the sudden death of your brothers but if your brother appeared in that dream and they are at the back of the house it means the death of sisters or relatives. If the dreamer was looking out of a window he or she will travel out of the country and succeed. 103-Ore ojiji mbo fun eniti o ri aburanda-unbrella loju orun. 103-UNBRELLA: Unexpected success is coming to the dreamer if she/he sees an umbrella. 23


104-POOSI kiise ohun ti o dara,aisan ni itumo re. 104-COFFIN: To dream of coffin is a sign of sudden death. 105-Riri Oko oju omi loju orun tumo si irinajo ti o dara. 105-SHIP: To dream of ship or boat signifies a good trip. 106-Riri inu igbo ti o kun fun opolopo ewe dara, sugbon bi ko ba si awon igi elewe pupo nibe o tumo si isora fun ibanilorukoje. 106-BUSH: Seeing of green bushes is a good tiding, if the bushes are bare of foliage, it is a sign of bad luck and scandal. 107-Ki enia ri opolopo eiye tumo si ejo ni kootu, sugbon ti awon eiye na ba nkorin,o tumo idunnu ati ife.Bi awon eiye na ba je dudu ti won nja tabi fo ori re koja kiise ala ti o dara.Ki o kun fun adua. 107-BIRDS: To see many birds denotes lawsuits, to hear birds singing foretells happiness and good news, to see black birds fighting or fly over your head is a bad omen. Pray hard against it. 108-Ki enia ri kirosi tumo ibanuje: sugbon bi kirosi na baje olomi Goolu, ifokanbale ninu igbeyawo ni itumo re, bi wahala ba wa ninu ile oko re, wahala na yio dopin laipe. Bi eni na ko ba ti loko tabi ni’yawo ki o kun fun adua ki o le ri oko tabi iyawo gidi fe. 108-CROSS: To dream you see a cross denotes sadness, golden cross foretells happiness in marriage, if you have married happiness will be in your marriage soon if you have problem with your husband, if you are single, pray hard to get a good husband. 109-:Tita ata loju ala tumo si iponju. 109-SELLING PEPPER: Selling pepper denotes sorrow. 110-Ki enia ri eni loju ala tumo si wahala. 110-MAT: Mat signifies trouble to the dreamer.

24


111- Ki enia ri Ade loju orun, iyi ati aponle ni itumo re. 111- CROWN: To dream of crown it signifies dignity and honour. Prayer or fasting and give alms may solve problems of any bad dream we have if you believe in God and have strong faith in prayers. Dauda Awwal 0044 746 67 67 942 dawwal@yahoo.com Facebook:Dauda Awwal 13/01/2018

25


YORUBA VERSION

26


OGORUNKAN ATI MOKANLA AWON ALA ATI ITUMO RE 111 MOST DREAMS AND INTERPRETATIONS BY DAUDA AWWAL 1-Bi enia bala ala pe oun ri Oorun ti o tan imole tabi Osupa onimole ni opolopo igba, eni na yio je olokiki laiye ti emi re ba gun. Bi o ba ri Oorun ti o wokun tabi osupa ti o wokun, ibanuje ati aisan ni itumo re. 2-Ti enia ba nri okunkun lopolopo igba, awon aburu fe sele si onitoun tabi ara ile re. Ki o kun fun adua. 3-Ti enia ba nta eja tutu tabi o gbe eja loju orun lopolopo igba, eni na yio ni owo tabua ki o to fi aiye sile. 4-Bi malu ba nle enia kiri loju orun tabi malu na kan an, awon ota idile iya tabi baba tabi awon ore nlepa emi eni na lati pa a. Ki eni na mura si oro ara re. 5-Eje riri loju orun fun aboyun kiise ala gidi, Ki o gbadua gidi lori oyun inu re. 6-Riri awon olopa loju orun tumo si owo. 7-Ki iyawo tabi oko ju oruka igbeyawo nu loju orun, kii se ala to dara. Ki won sora ki igbeyawo na ma daru. 8-Ki enia ma ba ara re ni ile itoju awon oku kiise ala to dara,iku ojiji tabi aisan ni itumo re. 9-Ki enia ma ri ero isoro-makirofonu ni opolopo igba loju orun tumo si ise oluwa. 10-Elede loju orun tumo si ikilo, ki eni na jinna si awon iwa ese ki o ma ba kabamo. 11-Ki enia ja si inu koto loju orun tumo si aisan nla. 12-Ija loju orun tumo si asasi lati owo awon ota, ki eni na kun fun adua iso.

27


13-Riri ogun loju orun tabi wiwa ni ile itaja-oogun lati fe gba alaye nipa ogun tumo si erenje tabi idunnu,ki enia lo ogun loju orun tumo si ipadanu owo,isegun ni itumo re ti ogun na ba koro. 14-Bi o ba la ala pe won ta oun ni ibon l’oju orun,kiise ala to dara.Awon ota nlepa emi re. 15-Ikudu loju orun tumo si akanti/aseti.Ododo ife laarin oko ati iyawo,ti eja ba wa ninu ikudu na,iyawo eniti o la ala na ma bi ibeji.Ti opo ba ala na,yio ri okunrin rere miran fe. 16-Bi enia da yepe si ara re tabi si ara eni mimo re tumo si abuku. Ki eni na sora nipa oro siso tabi ki o ma lo sibi ayeye ni asiko na. 17-Fifo bi eiye loju orun tumo si isegun ota tabi agbega lenu ise tabi agbega ninu ise Oluwa. 18-Pipo eje loju orun tumo si aisan tabi jije majele loju aiye. Ki eni na sora fun apeje. 19-Ifitipa bani lopo loju orun kiise ala to dara. Ki eni na sora fun ayanfe odale, ki o si kun fun adua lori adawole re. 20-Igun afara koja tumo si isegun lori awon isoro, ki eni na kun fun adua. 21—Riri ejo loju orun kiise ala to dara. Bi eni na ba ni oko tabi iyawo tabi afesona, ki o sora ki edeoyede-nla ma sele eyiti o le tu won ka.Bi o ba pa ejo loju ala tumo si isegun ota. 22-Ki won ma aba aboyun lopo loju orun lai mo eni na lewu. Ti o ba je eni mo,ki a kun fun adua. 23-Ki enia maa ri ara re tabi elomiran ni ihoho loju orun tumo iberu, sise onje loju orun tabi tita epa, ati riri igba tabi koko ibile tumo si aisan, airije, airimu ati airina,sugbon idunnu ni itumo re bi o ba ri arewa obinrin loju orun. 24-Ki ile wo loju orun mo enia mole tabi o wo lu eni mimo loju orun tumo si ifaseyin. 28


25-Ijamba oko loju orun tabi eje tumo si ajalu nla. 26-Ijamba-ina loju orun tumo si wahala lenu ise tabi lori adawole, ki eni na kun fun adua. 27-Poosi loju orun tumo iku ojiji ore tabi ebi, ki eni na kun fun adua iso. Bi asiko ti eni na la ala na ba bosi asiko ti o fe lo si ibi ayeye igbeyawo.Bi oko tabi iyawo ti won fe se igbeyawoo ba la ala na,enikan ninu won yio se aisan lehin igbeyawo won. 28- Olongbo dudu, aja dudu, eiye dudu tabi malu dudu tumo si ajalu lati owo awon aje. Ki eni na kun fun ajo iso ati eyonu aiye. 29-Iworan ni Sinima tabi iworan ninu ero amohunmu-aworan tabi laptop loju orun tumo si abuku ati asasi lati owo ota.Ki eni na kun fun adua. 30-Riri agadagodo nla tabi kekere lojuorun tumo si akoba, ki eni na kun fun adua ki won ma fi sinu tubu. Ti o ba ri ara re ninu tubu loju orun tumo idilowo awon ota lori adawole re. 31-Aseyori ni eyin riri loju orun. Ti egg ba sonu ki o so ahan re,bi o ba fo eyin, ibanuje gidi ni itumo re. 32-Ibanuje tabi Aisan ni riri iboji loju orun. Ti olowo ba la ala pe won bo oun mo inu saare, ki o kun fun adua ki o ma ku ni talaka,ti talaka ba nla ala pe won bo oun mo’nu saare,yio ni owo ki o to ku.Ti enia bari saare ki o sora fun aisan tabi ijanikule. 33- Ile iwosan tumo si aisan 34-Wiwo aso dudu tabi riri aso dudu loju orun tumo ibanuje nla laarin ebi. 35-Agbado riri loju orun/tabi orisirisi eso tabi gbigbe koto ti omi sun jade ninu re tumo si agbega ati aseyori. 36-Ki enia ma ri ara re lori oke nla tabi ninu osupa tumo si asiwaju/agbega.

29


37-Gigun esin loju orun tumo aseyori, agbega, erenje ati ibori ota. 38-Malu ti o tinrin-iyan, airije sugbon malu sisanra tumo orire ati ola. 39-Onje jije loju orun kiise ohun ti o dara. 40-Ki bata obinrin ti o ni oko tabi okunrin ti o ni iyawo sonu loju orun tumo si ajatuka laarin oko ati iyawo tabi afesona. 41-Ki Iborun obinrin sonu tabi aso ibora okunrin sonu loju orun tumo aibale okan ninu igbeyawo tabi afesona. 42-Alantakun loju orun tumo si isora fun iyawo/afesona tabi ore odale. 43-Akeke loju orun tumo si jamba ore. 44—Ki enia la ala pe enikan nbu oun, ala burburu ni: sugbon bi eniti o la ala na ba nbu enia loju orun aseyori ni itumo re. 45- Ki enia ri odo tabi eniti nmu igbo tabi siga tabi eniti nfoso tumo si idunnu. 46-Riri Ewa tabi jije ewa loju orun tumo si aisan tabi wahala. 47-Tolotolo nse ikilo nipa aisan nla. 48-Ki enia ma san owo fun oloja loju orun tumo si bibi omokunrin,bi owo ba junu lowo re,ayanfe re yio dale,Bi o ba he owo loju ala,wa se opolopo wahala ni asiko na. 49-Omi tomo tumo si oro idunnu. 50-Kiko leta loju orun tumo irohin idunnu 51-Ki enia ri Onirungbon ti o kun repete tumo owo, ti irungbon na ba kere, ki eni na sora fun oro ile-ejo. Bi Agbejoro tabi Onimimo tabi Ojogbon tabi Alfa-nla tabi Agba Pasto ba la ala ri Onirungbon kikun aseyori ni itumo re, sugbon bi omode ba la ala na wahala nla mbo fun u.Bi obinrin ti ko ni oko ba la ala pe oun ni’rugbon,oko re yio ku,ayafi ki o kun fun adua. 30


52-Ki enia ri ile ifowopamo ala na nse ikilo idawole owo sise. 53-Ki enia ri Ikoerusi/bag tumo si aisan, bi o ba gbe bagi kolofo tumo si osi,bi o ba gbe eyiti owo die wa ninu re tumo si nini owo die. 54-Orun sisun labe igi tumo si ajalu buruku. Bi enia basun labe igi ti oni opolopo ewe tumo si ifeyawo tabi loko.wahala ni ki enia ri ara re labe igi ti ko ni ewe. 55-Ategun tumo igbadun sugbon ategun agan tumo si wahala, ogun aiye. 56-Omu/Oyan.Bi o ba ri oyan re ti o rewa, ala daradara ni,sugbon abileko ba nri oyan re lopolopo igba, yio padanu oko re. 57-Ki enia sora fun ijamba oko tabi iku ojiji bi enia ba ri oko ojurin/train loju ala. 58-Masalasi: Eniti o ri masalasi loju ala ti o si je musulumi, ki eni na ma fi esin re sile, idunnu mbo fun u. Sosi: Ti kirisiteni ba ri ara re ni ile isin, idunnu kan mbo fun u. 59-Bi o ba la ala pe won ta o ni ofa ti eje ko jade lara re, ore ojiji kan mbo wa fun o lati odo eniti o ta o lofa loju orun, sugbon bi o ba fi ara pa die, oore na si ma wa teo lowo. 60-Ti enia ba ri karoti loju ala yio ri opolopo ere lori adawole re. 61-Riri adan loju orun tumo ibanuje, ki eni na sora fun eletan. 62-Wiwe loju orun tumo ibanuje ati aisan, sugbon wiwe lodo tumo si ibanuje ojo iwaju ti ombo, ki eni na kun fun adua sugbon bi ori eniti o nwe lodo ba yo sita,aseyori ni itumo re. 63-Ki won ju enia ni okuta loju ala nse ikilo ki eni na so ahan re. 64-Bi olowo ba la ala pe oun banuje loju orun,o tumo si ifi arapa,ti olosi ba la a,yio ri iranlowo lati odo olowo. 65-Orin kiko loju orun tumo si ibanuje sugbon bi o ba gbo ohun orin kiko eyi tumo si Alaafia alamodi. 31


66-Riri Aja loju orun ti ko ba gbo mo o, ala ti o dara ni,o tumo ife, sugbon bi o ba gbo ti o sibu o je,ota fe pa o ni.Ki o kun fun adua ki o si toju arare. 67-Ki enia lala pe oun joba-de ade tumo si aisan. Ki eni na kun fun adua. 68-Oruka: Bi aboyun ba lala ri oruka loju orun, omo inu re yio se wahala pupo ki o to di enia gidi lawujo, bi obinrin ti o ni afesona ba ri oruka loju orun ki o sora ki afesona re ma dale re. Bi oruka ba sonu lowo iyawo tabi oko, enikan ninu awon mejeji ma ku,ki won kun fun adua.Bi enia ba ri oruka lowo ara re,o tumo si iyi ati agbega,sugbon bi eni na ko ba ti loko tabi fe iyawo, o lewu.Eniti o nse ise ti o lodi si ofin ilu ti o wa:ti o ba la ala pe oruka sonu lowo oun, ewon ni itumo re. 69-Ile onje-:Ki enia ma jeun ni ile onje loju orun tumo si aisan. 70-Eni ti o nri Ehoro loju orun lopolopo igba, ki o mura si oro ile aiye re,bi beeko,ki yio je enia gidi ti yio fiku. 71-Eniti o ba la ala pe oun ni edeoyede pelu enikeni tumo si irohin airotele. 72-Ki eniti ma ko leta loju orun tumo si aseyori sugbon ki enia ma pin leta lati ojule si ojule ki eni na sora kuro nipa itenubole kiri ati ofofo ki aburu nla ma sele si eni na. 73-Bi enia ba ri irori ti eje wa lara re tumo si iku olori ebi eni won nibi ijamba oko, ti irori na bamo, idunnu ati aseyori ni itumo re. 74-Elede tumo si ilara awon ore. sugbon ti enia ba nta elede loju orun tumo si aisan,ki eni na ma da wole owo lasiko na,bi beeko ofo ni. 75-Ago loju orun tumo aisan ,ti ago na ko ba sise ki eni na ma da wole owo sise lasiko na ti ko ba fe padanu.Bi alamu ago na ba dun,aseyori ni itumo re. 76-Edie Didin loju orun tumo aisan, ti eniti o la ala na ba je agbe, opolopo eso tabi ile edie re ninu oko ni yio s’ofo . 32


77-Bi enia ba ri Olongbo ki o sora fun awon olosa abele,bi eni na ba pa olongbo loju ala tabi o rinna pade olongbo, ki eni na sora ki o ma jale eyiti o le ran an lo si ewon,bi enia ba je olongbo loju ala,yio ri dukia re ti ole gbe,ti eni na ba ja loju orun pelu olongbo ti olongbo si se e lese, aisan nla ni itumo re.Ki eni na kun fun adua. 78-Bi Awo onje ba fo lowo enikeni loju orun, inkan nla ma sonu lowo re tabi ki okan ninu awon ebi se aisan. 79-Riri Agbe tabi Dokita tabi Nosi tabi igo-oju loju orun tumo idunnu. 80-Okiki ni gbigbo ohun ilu loju orun 81-Ki enia fun Eerin lonje loju orun tumo si ise lodo gbajumo ilu.Bi o ba nsise pelu pelu olola ni asiko na won yio gbe e ga. 82-Riri opolopo eja loju orun tumo alaafia ati opolopo owo.Bi eniti ko ni oko tabi iyawo ba nri eja lopolopo igba, eni na yio ri iyawo tabi oko gidi fe.Bi aboyun ba bi oku eja loju orun,yio bi omo inu re loku.Bi enia ba de ogere sinu odo lati mu awon eja,ajalu buruku ni itumo re. 83-Ki enia pa opolo tabi mu opolo loju orun tumo si wahala tabi iku ojiji, bi eni na ba ni oko tabi iyawo,bi eniti ko loko tabi iyawo ba la ala na,ki o sora fun awon olofofo.Idunnu ni opolo fun agbalagba ti o ba ri opolo loju orun. 84-Ki enia ri igi ti okun fun opolopo ewe tutu tumo si idunnu. 85-Igbeyawo loju orun tumo si aisan tabi iku ojiji: bi okunrin ba fe aburewa obinrin,iku ojiji ni itumo re,ki o se opolopo adua,bi o ba je arewa obinrin,idunnu ni itumo re,bi eni ti o la ala na ba je oluranlowo nibi ayeye igbeyawo,iro idunnu mbo fun eni na. 86-Ki enia ma mu miliki loju orun tumo si idunnu ati aseyori ati opolopo omo, ki enia ma fi miliki sofo loju orun, ala buruku ni eyi.Ki enia ma ta miliki loju orun tumo ife laarin eniti o la ala ati olufe re.

33


86-Ki enia ri oko ti o nsise daradara loju orun tumo aseyori ati agbega, sugbon ti oko na ko ba sise,kiise itumo ti o dara.wahala mbo, ki eni na fi adua jagun. 87-Alupupu: Mavfi oro iba-obinrin re lopo tabi iba-okunrin re lopo jafara. 88-Riri keke loju orun tumo si igbadun lehin opolopo wahala, ki o se opolopo adua ki o ma ba ri wahala.. 89-Ki enia ri okunrin/obinrin ni ihoho tumo si wahala,sugbon ti eni na ba ri obinrin pupa ni ihoho,idunnu ni itumo re,bi obinrin na ba je dudu tabi aburewa tabi arugbo dudu idojuti ati ijakule ni itumo re.Bi oko ba nri iyawo re ni ihoho lopolopo igba,eletan ni iyawo re,sugbon bi iyawo ba nri oko re ni ihoho lopolopo igba,aseyori fun oko re ni o tumo si.Bi o ba ri ore re ni ihoho,ija yio sele laarin yin.Bi o ba ri ara re ni ihoho,sora fun airina tabi aisan fun olowo,bi o ba ri ara re ni ihoho ninu masalasi tabi church ala buruku ni. 90-Abere tabi epa loju orun tumo si aseyori. 91- Jije Alubosa loju orun tumo si idunnu ati ibanuje. Kun fun adua 92-Riri Osan tabi mimu u tumo si ibanuje, ki eni na kun fun adua. 93-Ki enia ri beba lopolopo igba tumo si owo nini. 94-Ki enia ma ge irun fun enia kan ti o je ojulumo,eniti won ke irun fun na yio se aseyori lori nkan ti o da wole lasiko na,sugbon ki won ma ke irun tabi diri fun eniti o la ala,kiise itumo ti o dara fun eni naajakule nitumo re. 95-Aguntan:Ki enia ni opolopo aguntan loju orun tumo si ini opolopo dukia/owo 96- Ki enia so kokoro nu loju orun tumo si ileni kuro lenu ise tabi ki eni na padanu owo. 97-Ija ina loju orun tumo ofo.

34


98-Eiyele/Ataba tumo idunnu ati alaafia 99-Ki enia gba oyin tabi fun enia loyin loju orun tumo si aseyori. 100-Ki enia ri opolopo oke ti o yii ka tumo si isegun ota. 101-Ki enia ri igbale loju orun tumo si iso ebi po.Enikan fe lo anfani re fun ara re ni ona ti ko dara lenu ise. 102-Bi enia ba ri ferese iwaju ile ti o gbina,eniti o la ala na ma padanu egbon tabi aburo re okunrin,sugbon ti awon arakunrin re na ba wa ninu ala na, ti won si wa lehinkunle ile na,awon aburo/egbon re lobinrin tabi ebi kan ni yi o ku lojiji.Bi enia ba nyoju sita lati oju ferese,eni na yio se irinajo losi ilu okere,yio si se orire ki o to pada si ilu baba re. 103-Ore ojiji mbo fun eniti o ri aburanda-unbrella loju orun. 104-POOSI kiise ohun ti o dara,aisan ni itumo re. 105-Riri Oko oju omi loju orun tumo si irinajo ti o dara. 106-Riri inu igbo ti o kun fun opolopo ewe dara, sugbon bi ko ba si awon igi elewe pupo nibe o tumo si isora fun ibanilorukoje. 107-Ki enia ri opolopo eiye tumo si ejo ni kootu, sugbon ti awon eiye na ba nkorin,o tumo idunnu ati ife.Bi awon eiye na ba je dudu ti won nja tabi fo ori re koja kiise ala ti o dara.Ki o kun fun adua. 108-Ki enia ri kirosi tumo ibanuje: sugbon bi kirosi na baje olomi Goolu, ifokanbale ninu igbeyawo ni itumo re, bi wahala ba wa ninu ile oko re, wahala na yio dopin laipe. Bi eni na ko ba ti loko tabi ni’yawo ki o kun fun adua ki o le ri oko tabi iyawo gidi fe. 109-:Tita ata loju ala tumo si iponju. 110-Ki enia ri eni loju ala tumo si wahala. 111- Ki enia ri Ade loju orun, iyi ati aponle ni itumo re.

35


Prayer or fasting and give alms may solve problems of any bad dream we have if you believe in God and have strong faith in prayers. Dauda Awwal 0044 746 67 67 942 dawwal@yahoo.com Facebook:Dauda Awwal 13/01/2018

36


ABOUT THE AUTHOR Dauda Awwal is a prayer warrior and very intelligent and focus, dynamic and multi-talented. He can co-exist with people of different beliefs and purpose to accomplish both human and ethnic language. Awwal is a product of Anglia Ruskin University, Cambridge, United Kingdom 2016.Awwal is product of CRTS International College, Tottenham, London where he bagged F.C.E & C.A.E. Awwal also attended many courses in England. He holds HND on Linguistics, National Upper Diploma on Investigative journalism, news writing and film production. Awwal holds many credits from the General Federation of Trade Union (GFTU)'s courses, such as Desktop Publishing, GFTU Basic Representative Court, GFTU dealing with changes to employment law, GFTU Understanding Company Accounts, GFTU Leadership Skills, GFTU Managing Successful Project, October 2013, GFTU Dealing with stress and conflict in the workplace, 0ct 2013, GFTU Managing Successful project October 2013, GFTU Dealing with bullying Harassment and Stress October 2013, Reps Officer 2014. ABOUT THE BOOK Dreams come for instructions, warning, directions, teaching, messages. Dreams don’t always tell a simple story, and sometimes the field of dream research becomes more fascinating when people from different cultures and backgrounds report having similar dreams. There are meaning for symbols and images in dreams. Some dreamers have: Pre-cognitive Dreams: These are psychic dreams that can foretell the future. Some have Warning Dreams: These dreams alert them to possible danger or problems ahead. Therefore, I brought to you in this book 111 Dreams and the meaning. Here are the most common 111 dream symbols, and their meanings in Yoruba and English. I hope this book will be useful at all levels. Dauda Awwal 13/01/2018 -----------------------------------------------------------Reference: Quran and Bible/ Dreams by Edwin Rahael/Story of Joseph by Dauda Awwal.

37


FREE PAGE

38


Turn static files into dynamic content formats.

Create a flipbook
Issuu converts static files into: digital portfolios, online yearbooks, online catalogs, digital photo albums and more. Sign up and create your flipbook.