Habakuku
ORI1
1ỌRỌtíHábákúkùwòlíìrí 2Oluwa,yiotipẹtotiemiomakigbe,tiiwọ kìyiosigbọ!anikigbesiọtiìwa-agbara,iwọ kìyiosigbà!
3Ẽṣetiiwọfiẹṣẹhànmi,tiiwọsimumiri ibinujẹ?nitoriikogunatiiwa-ipambẹniwaju mi:atiawọntioruìjaatiìjadide.
4Nitorinaliofinṣedẹṣẹ,idajọkòsijadelọ lae:nitorieniabuburuyiolododoka;nitorina idajọtikotọtẹsiwaju
5Kiyesii,ẹnyinlãrinawọnkeferi,kiẹsi kiyesii,kiẹsiṣeiyanu:nitoriemioṣiṣẹiṣẹ kanliọjọnyin,tiẹnyinkìyiogbagbọ,biatilẹ wifunnyin.
6Nitorikiyesii,emigbeawọnaraKaldea dide,orilẹ-èdekikoròatiakikanju,tiyiorìn ibúilẹnajá,latigbàibujokotikìiṣetiwọn
7Nwọnliẹruatiẹru:idajọwọnatiọláwọn yiotiọdọarawọnjadewá
8Ẹṣinwọnpẹluyarajuẹkùnlọ,nwọnsirójù ikõkòaṣalẹlọ:awọnẹlẹṣinwọnyiosinàara wọnka,awọnẹlẹṣinwọnyiositiokerewá; nwọnofòbiidìtioyaralatijẹ.
9Gbogbowọnyóòwáfúnìwàipá:ojúwọn yóòyọbíẹfúùfùìlà-oòrùn,wọnyóòsìkó ìgbèkùnjọbíiyanrìn
10Nwọnosifiawọnọbaṣeyẹyẹ,awọnijoye yiosijẹẹganfunwọn:nwọnosifigbogbo agbaramu;nitorinwọnosiheapekuru,nwọn osimuu.
11Nigbanaliọkànrẹyioyipada,yiosirekọja, yiosiṣẹ,yiokaagbararẹsieyisiọlọrunrẹ.
12Iwọkìiṣelatiaiyeraiye,OluwaỌlọrunmi, Ẹni-Mimọmi?akìyóòkú.Oluwa,iwọlioti yànwọnfunidajọ;ati,Ọlọrunalagbara,iwọti fiidiwọnmulẹfunatunṣe.
13Iwọniojutiomọjulatiwoibilọ,atipe iwọkòlewoaiṣedede:niboniiwọtinwò wọntioṣearekereke,tiosimuahọnrẹmu nigbatiawọneniabuburubajẹọkunrintiojẹ olododojùulọ?
14Tiosiṣeeniabiẹjaokun,biohuntinrakò, tikònioloriloriwọn?
15Nwọnfiigunmugbogbowọn,nwọnsimu wọnsinunetwọn,nwọnsikówọnjọnifà wọn:nitorinanwọnyọ,inuwọnsidùn.
16Nitorinaninwọnṣerubọsiàwọnwọn, nwọnsisunturarifunfifawọn;nitorinipa wọnniipinwọnsanra,atiẹranwọnli ọpọlọpọ.
17Njẹnwọnhahasọàwọnwọndiofo,ki nwọnkiomásidasinigbagbogbolatipa awọnorilẹ-èderunbi?
ORI2
1EMIoduroloriiṣọmi,emiosigbemile oriile-iṣọ,emiosimaṣọnalatiriohuntiono wifunmi,atiohuntiemiodahunnigbatiaba bamiwi
2OLUWAsidamilohùn,osiwipe,Kọìran na,kiosifihàngbangbaloritabili,kiẹnitio kàabalesare.
3Nitoriirannawàfunakokòtiayàn,ṣugbọn liopinyiosọrọ,kìyiosipurọ:biotilẹduro, durodèe;nítorípédájúdájúyóòdé,kìyóò dúró
4Kiyesii,ọkànrẹtiogbegakòduroṣinṣin ninurẹ:ṣugbọnolododoyioyènipaigbagbọ rẹ.
5Pẹlúpẹlù,nítorípéóńfiọtírúbọ,ójẹ agbéraga,kòsìdúrósíilé,ẹnitíómúìfẹrẹ gbòòròbíipòòkú,tíódàbíikú,tíkòsìlètẹẹ lọrùn,ṣùgbọnókógbogboorílẹ-èdèjọsọdọ rẹ,tíósìkógbogboorílẹ-èdèjọsọdọrẹ. eniyan:
6Gbogboawọnwọnyikìyiohapaaowesii, atiẹgansii,wipe,Egbenifunẹnitionsọ eyitikìiṣetirẹpọsi!Bawolosegunto?ati funẹnitiofiamọnipọndiararẹ.
7Awọntiyiobùọkìyiohadidelojiji,ti nwọnosijíọ,tinwọnosimuọbibi,iwọosi diikogunfunwọn?
8Nitoritiiwọtibaorilẹ-èdepupọjẹ,gbogbo awọneniaiyokùyiosikóọ;nitoriẹjẹenia,ati nitoriìwa-ipailẹna,tiilu,atitigbogboawọn tingbeinurẹ.
9Egbenifunẹnitioṣojukokoroojukokoro buburusiilerẹ,kioletẹitẹrẹsiibigiga,kio lebọlọwọagbaraibi!
10Iwọtigbìmọìtìjúsiilerẹnipakeenia pupọkuro,iwọsitiṣẹsiọkànrẹ
11Nitoripeokutayiokigbelatioriodiwá,ati igilatiinuiginayiosidaalohùn.
12Egbenifunẹnitiofiẹjẹkọilu,tiosifi ẹṣẹmuilukanlelẹ!
13Kiyesii,kìiṣelatiọdọOluwaawọnọmọogunliawọneniayioṣelãlaninuinána,ati awọnenianayiosirẹarawọnfunasan gidigidi?
14NitoripeaiyeyiokúnfunìmọogoOluwa, biomitibòokun
15Egbénifunutiofunaladugborẹmu,tio fiigorẹfunu,kiosimuumupẹlu,kiiwọki olewoìhohowọn!
16Iwọkúnfunitijufunogo:iwọpẹlumu,si jẹkiadọdọrẹtú:agoọwọọtúnOluwaliao yisiọ,atiitọitijuyiowàloriogorẹ.
17Nitoripeìwa-ipaLebanoniyiobòọmọlẹ, atiikogunẹranko,tiodẹrubawọn,nitoriẹjẹ enia,atinitoriìwa-ipailẹna,tiilu,atiti gbogboawọntingbeinurẹ.
18Èrèkínièretíẹnitíóṣeéfigbẹèrenáà? èredídà,atiolùkọeke,tiẹnitíóṣeiṣẹrẹfi gbẹkẹlérẹ,látiyáàwọnòrìṣàodi?
19Egbenifunẹnitiowifunigipe,Ji;si okutaodi,Dide,yiomakọni!Kiyesii,afi wuraatifadakabòo,kòsisiẽmiraraninurẹ.
20ṢugbọnOluwambẹninutẹmpilimimọrẹ: jẹkigbogboaiyedakẹniwajurẹ.
ORI3
1ÀdúràwòlíìHábákúkùlóríṢígíóótì.
2Oluwa,emitigbọọrọrẹ,ẹrusibàmi: Oluwa,sọiṣẹrẹsọjiliagbedemejiọdun,li ãrinọdunsọji;ninuibinurantianu
3ỌlọruntiTemaniwá,atiẸni-Mimọlatiòke Paraniwá.Sela.OgoReboawonorun,ayesi kunfuniyinre.
4didanrẹsidabiimọlẹ;óníìwotíńtiọwọrẹ jáde:ósìfiagbárarẹpamọníbẹ.
5Àjàkálẹ-àrùnńlọníwájúrẹ,àtiẹyíninásì jádelọlẹsẹrẹ
6Osiduro,osiwọnaiye:owòo,osifọ awọnorilẹ-èderun;asitúawọnoke-nla aiyeraiyeká,awọnòkeaiyeraiyesitẹriba:ọna rẹdurolailai.
7MoriagọKuṣanininuipọnju;aṣọ-titailẹ Midianisiwarìri.
8Oluwahabinusiawọnodòbi?ibinurẹsi awọnodòbi?Ibinurẹhaṣesiokun,tiiwọfi gùnẹṣinrẹ,atikẹkẹigbalarẹbi?
9Asọọrunrẹdiihohopatapata,gẹgẹbiibura awọnẹya,aniọrọrẹ.Sela.Ìwọtifiodòlailẹ ayé.
10Awọnòkeriọ,nwọnsiwarìri:àkúnwọn omikọjalọ:ibúfọohùnrẹ,osigbéọwọrẹ sokesioke.
11Õrùnonoṣupadurojẹniibujokowọn:ni imọlẹọfàrẹnwọnlọ,atinididánọkọrẹti ntàn.
12Iwọfiibinurinilẹnajá,iwọsifiibinupa awọnkeferipa.
13Iwọjadelọfunigbalaawọneniarẹ,ani funigbalapẹluẹni-orororẹ;iwọtiṣáori lọgbẹkuroniileeniabuburu,nipafifiipilẹ silẹdeọrùn.Sela.
14Iwọliofiọpárẹluawọnoloriiletorẹ: nwọnjadebiìjilatitúmika:ayọwọndabiati patalakarunniìkọkọ.
15Iwọtifiawọnẹṣinrẹrìnliokunjá,liokiti ominla.
16Nigbatimogbọ,ikùnmiwarìri;Ètèmi gbọn-ọngbọn-ọn-gbọn-ọn-gbọn-ọn-ọrọ:ìbàjẹ sìwọinúegungunmilọ,èmisìwárìrìnínú arami,kíèmilèsinminíọjọìpọnjú:nígbàtí óbágòkètọàwọnènìyànnáàwá,òunyóòsì gbóguntìwọnpẹlúàwọnọmọogunrẹ.
17Biigiọpọtọkìyiotitanna,bẹliesokìyio sitanninuàjara;iṣẹigiolifiyóògbilẹ,àwọn okokìyóòsìmúoúnjẹwá;aokeagbo-ẹran kuroninuagbo,kiyiosisiọwọ-ẹranninu awọnibusọ;
18ṢugbọnemioyọninuOluwa,emiomayọ ninuỌlọrunigbalami.
19OluwaỌlọrunliagbarami,onosiṣeẹsẹ mibiẹsẹagbọnrin,yiosimumirìnloriibi gigami.Sioloriakọrinloriohun-elookùnmi.