Yoruba - The Book of Prophet Jonah

Page 1


Jona

ORI1

1NIGBANAliọrọOluwatọJonaọmọAmittaiwá,wipe, 2Dide,lọsiNinefe,ilunlanì,kiosikigbesii;nitoriìwabuburuwọngokewásiwajumi

3ṢugbọnJonadidelatisalọsiTarṣiṣikuroniwajuOluwa, osisọkalẹlọsiJoppa;osiriọkọkantinlọsiTarṣiṣi:osi sanoworẹ,osisọkalẹsinurẹ,latibawọnlọsiTarṣiṣi kuroniwajuOluwa.

4ṢùgbọnOlúwaránẹfúùfùńláǹlàjádesínúòkun,ìjìńlásì múnínúòkun,tóbẹẹtíọkọnáàfẹfọ

5Nigbanaliẹrubaawọnatukọ,olukulukusikigbesi ọlọrunrẹ,nwọnsidaẹrùtiowàninuọkọsinuokun,lati muufúyẹṢugbọnJonasọkalẹlọsiẹgbẹọkọ;osidubulẹ, osisùnfọnfọn.

6Bẹnibalogunọkọtọọwá,osiwifunupe,Kiniiwọnfẹ, iwọorun?dide,kepeOlorunre,biOlorunbarowa,kia masegbe.

7Olukulukuwọnsiwifunẹnikejirẹpe,Wá,jẹkiaṣẹ keké,kiawakiolemọnitoritaniibiyiṣewásoriwaBẹẹ niwọnṣẹgègé,kèkésìmúJónà.

8Nigbananinwọnwifunupe,Sọfunwa,awabẹọ,nitori taniibiyiṣesoriwa;Kiniiṣẹrẹ?niboniiwọsitiwá? orilẹ-edewoni?atininueniawoniiwọiṣe?

9Osiwifunwọnpe,Heberuliemi;emisibẹruOluwa Ọlọrunọrun,tiodaokunatiiyangbẹilẹ 10Nigbanaliawọnọkunrinnabẹrugidigidi,nwọnsiwi funupe,Ẽṣetiiwọfiṣeeyi?Nitoritiawọnọkunrinnamọ peonsákuroniwajuOluwa,nitoritiotisọfunwọn

11Nigbananinwọnwifunupe,Kiliawaoṣesiọ,kiokun kioledakẹfunwa?nitoritiokunru,osiru

12Osiwifunwọnpe,Ẹgbémisoke,kiẹsisọmisinu okun;bẹniokunyiosidakẹfunnyin:nitoritimomọpe nitoriminiìjìnlayiṣewásorinyin

13Ṣugbọnawọnọkunrinnafiọkọkikanralatimuwásiilẹ na;ṣugbọnnwọnkòleṣee:nitoritiokunru,osirusiwọn.

14NitorinanwọnkigbepèOLUWA,nwọnsiwipe,Awa mbẹọ,Oluwa,awambẹọ,máṣejẹkiaṣegbenitoriẹmi ọkunrinyi,másiṣefiẹjẹalaiṣẹlewalori:nitoriiwọ, Oluwa,tiṣebiotiwùúiwo

15BẹninwọngbéJona,nwọnsisọọsinuokun:okunsi dẹkunrirurẹ

16NigbanaliawọnọkunrinnabẹruOLUWAgidigidi, nwọnsiruẹbọsiOLUWA,nwọnsijẹẹjẹ.

17OLUWAsitipeseẹjanlakanlatigbeJonamìJonasi wàninuikùnẹjanafunọsánmẹtaatiorumẹta

ORI2

1NIGBANAniJonagbadurasiOluwaỌlọrunrẹlatiinu ẹjanawá

2Osiwipe,EmikigbenitoriipọnjumisiOLUWA,osi gbọtiemi;latiinuisàokúwánimokigbe,iwọsigbọohùn mi

3Nitoritiiwọtisọmisinuibu,liãrinokun;omi-omisiyi mikakiri:gbogboriruomirẹatiriruomirẹkọjalorimi.

4Nigbananimowipe,Atamikuroniwajurẹ;sibẹemio tunwotẹmpilimimọrẹ

5Omiyimikakiri,anideọkàn:ọgbunsémikakiri,ayi èpoyimika

6Mosọkalẹlọsiisalẹawọnòke;aiyepẹluọpáidaburẹwà yimikatitilai:ṣugbọniwọtimúẹmimigòkekuroninu idibajẹ,OluwaỌlọrunmi

7Nigbatiãrẹọkànmininumi,emirantiOluwa:adurami siwọletọọwá,sinutempilimimọrẹ

8Àwọntíwọnńkíyèsíàwọnohunasántikọàánúara wọnsílẹ.

9Ṣugbọnemiofiohùnọpẹrubọsiọ;Èmiyóòsanèyítí motijẹjẹẹTiOluwaniigbala

10OLUWAsisọfunẹjana,osibìJonajadesoriiyangbẹ ilẹ

ORI3

1ỌRỌOluwasitọJonawálẹkeji,wipe, 2Dide,lọsiNinefe,ilunlanì,kiosiwasuiwasunatimo palaṣẹfunọfunu

3Jonasidide,osilọsiNinefe,gẹgẹbiọrọOluwaNineve sijẹilunlationiìrinijọmẹta.

4Jonasibẹrẹsiwọinuilunalọniìrinijọkan,osikigbe, osiwipe,Siiliogojiọjọ,aosibìNinefeṣubu.

5BẹẹniàwọnaráNínéfègbaỌlọrungbọ,wọnsìkéde ààwẹ,wọnsìwọaṣọọfọ,látioríẹnitíótóbijùlọtítídéẹni tíókéréjùlọnínúwọn

6NitoritiọrọnatọọbaNinefewá,osidideloriitẹrẹ,osi bọaṣọigunwarẹkurolararẹ,osifiaṣọ-ọfọbòo,osijoko ninuẽru

7Ósìmúkíwọnkéderẹ,kíwọnsìkéderẹníNínéfènípa àṣẹọbaàtiàwọnìjòyèrẹpé,“Kíènìyàntàbíẹranko,agbo màlúùtàbíagboẹranmáṣetọnǹkankanwò.

8Ṣugbọnjẹkieniaatiẹrankofiaṣọ-ọfọbora,kinwọnkio sikigbekikansiỌlọrun:nitõtọ,jẹkinwọnyipada, olukulukukuroniọnabubururẹ,atikuroninuìwa-ipatio wàlọwọwọn.

9TaliolemọbiỌlọrunyioyipada,kiosironupiwada,ki osiyipadakuroninuibinugbigbonarẹ,kiawakiomába ṣegbe?

10Ọlọrunsiriiṣẹwọn,tinwọnyipadakuroniọnabuburu wọn;Ọlọrunsironupiwadabuburu,tiotisọpeonoṣesi wọn;kòsìṣeé

ORI4

1ṢùgbọnóbíJónànínúgidigidi,ósìbínúgidigidi

2OsigbadurasiOluwa,osiwipe,Emibẹọ,Oluwa,kìiṣe eyiliọrọmi,nigbatimowàniilẹmisibẹ?Nitorinanimo ṣesalọsiTarṣiṣi:nitoritimomọpe,Ọlọrunolore-ọfẹ,ati alãnuniiwọ,olọralatibinu,atiolorenla,osironupiwada ibi

3Njẹnisisiyi,Oluwa,emibẹọ,gbaẹmimilọwọmi;nítorí ósànfúnmilátikújulátiwàláàyèlọ.

4OLUWAsiwipe,Ohadarakiobinubi?

5Jonasijadekuroniiluna,osijokoniìhaìla-õrùniluna, osiṣeagọkannibẹfunu,osijokolabẹojijirẹ,titionofi riohuntiyioṣeiluna

6OlúwaỌlọrunsìpèsèìtàkùnkan,ósìmúkíógòkèwá sóríJónà,kíólèjẹòjìjilórírẹ,látigbàálọwọìbànújẹrẹ. BẹniJonayọgidigidinitoriìtàkùnna

7ṢùgbọnỌlọrunpèsèkòkòròkannígbàtíilẹmọníọjọ kejì,ósìluìtàkùnnáàtíórọ.

8Osiṣe,nigbatiõrunlà,Ọlọrunsipèseẹfũfulileìla-õrùn; òòrùnsìluJónàlórí,ósìdákú,ósìfẹkúnínúararẹ,ósì wípé,“Ósànfúnmilátikújulátiwàláàyèlọ

9ỌlọrunsiwifunJonape,Ohadarakiiwọkiobinu nitoriitakunna?Onsiwipe,Odarakiemikiobinu,ani titideikú

10NígbànáàniOlúwawípé,“Ìwọṣàánúìtàkùnnáà,nítorí èyítíìwọkòṣiṣẹ,tíìwọkòsìmúkíódàgbà;tíógòkèwá níòrukan,tíósìṣègbéníòrukan

11ÈmikìyóòsìdáNinefesí,ìlúńlánáà,nínúèyítíóléní ọkẹmẹrinènìyàntíkòlèmọláàrínọwọọtúnàtiọwọòsì wọn;atikiotunEloẹran?

Turn static files into dynamic content formats.

Create a flipbook
Issuu converts static files into: digital portfolios, online yearbooks, online catalogs, digital photo albums and more. Sign up and create your flipbook.