Rutu
ORI1
1OSIṣeliọjọtiawọnonidajọṣeidajọ,tiìyanmúniilẹna. ỌkunrinkanaráBetlehemu-judasilọṣeatiponiilẹMoabu, on,atiayarẹ,atiawọnọmọrẹọkunrinmejeji
2OrukọọkunrinnasinjẹElimeleki,atiorukọayarẹ Naomi,atiorukọawọnọmọrẹọkunrinmejejiMaloniati Kilioni,araEfratitiBetlehemu-judaNwọnsiwásiilẹ Moabu,nwọnsijokonibẹ.
3ElimelekiọkọNaomisikú;osikù,atiawọnọmọrẹ mejeji
4NwọnsifẹayaninuawọnobinrinMoabu;orukọekinisi njẹOrpa,orukọekejisiniRutu:nwọnsijokonibẹniwọn ọdúnmẹwa
5MaloniatiKilionisikúpẹlu;obinrinnasikùninuawọn ọmọkunrinrẹmejejiatiọkọrẹ
6Nigbanaliodidepẹluawọnaya-ọmọrẹ,kiolepadalati ilẹMoabu:nitoritiotigbọniilẹMoabupe,Oluwatibẹ awọneniarẹwònififunwọnlionjẹ
7Nitorinaliosijadekuroniibitiogbéwà,atiawọnayaọmọrẹmejejipẹlurẹ;wñnsìlæðnàlátipadàsíilÆJúdà.
8Naomisiwifunawọnaya-ọmọrẹmejejipe,Ẹlọ, olukulukusiileiyarẹ:kiOLUWAkioṣeorefunnyin, gẹgẹbiẹnyintiṣesiokú,atifunmi.
9KiOLUWAkiofifunnyinkiẹnyinkioleriisimi, olukulukunyinniileọkọrẹNigbanaliofiẹnukòwọnli ẹnu;nwọnsigbéohùnwọnsoke,nwọnsisọkun.
10Nwọnsiwifunupe,Nitõtọawaobaọpadalọsọdọ awọneniarẹ
11Naomisiwipe,Ẹyipada,ẹnyinọmọbinrinmi:ẽṣeti ẹnyinofibámilọ?ṣéàwọnọmọkùnrintúnwànínúmi,kí wọnlèjẹọkọyín?
12Ẹyipada,ẹnyinọmọbinrinmi,ẹmãbaọnanyinlọ; nítorímotidàgbàjùlátiníọkọBimobawipe,Eminiireti, biemibaniọkọpẹlulialẹyi,tiemiosibiọmọkunrinpẹlu; 13Ẹnyinohadurodewọntitinwọnofidàgbabi?ẹnyino hadurofunwọnlatiniọkọbi?Bẹẹkọ,awọnọmọbinrinmi; nítoríóbàmínínújẹpúpọnítoríyínpéọwọOlúwatijáde sími
14Nwọnsigbéohùnwọnsoke,nwọnsitunsọkun:Orpasi fiẹnukòiyaọkọrẹliẹnu;ṣugbọnRutufàmọọn.
15Onsiwipe,Kiyesii,arabinrinọkọrẹtipadatọawọn eniarẹlọ,atisọdọawọnoriṣarẹ:kiiwọkiositọarabinrin ọkọrẹlẹhin.
16Rúùtùsìdáhùnpé,“Máṣebẹmípékínfiọsílẹ,tàbíkí npadàlẹyìnrẹatinibitiiwọbawọ,liemiowọ:awọnenia rẹniyiomaṣeeniami,atiỌlọrunrẹỌlọrunmi; 17Nibitiiwọbakú,liemiokú,nibẹliaosisinmi:ki OLUWAkioṣebẹsimi,atijùbẹlọpẹlu,biikúbayàiwọ atiemi.
18Nigbatiosiripeontipinnurẹṣinṣinlatibáonlọ, nigbanaliofiọrọbaasọrọsilẹ 19BẹẹniàwọnméjèèjìlọtítíwọnfidéBẹtílẹhẹmù.Ósì ṣe,nígbàtíwọndéBẹtílẹhẹmù,gbogboìlúsìdàrúyíwọn ká,wọnsìwípé,“ṢéNáómìnìyí?
20Osiwifunwọnpe,ẸmáṣepèminiNaomi,ẹmapèmi niMara:nitoritiOlodumareṣesimigidigidi
21Emijadenikikun,Oluwasitunmumipadasiileliofo: ẽṣetiẹnyinfinpèminiNaomi,nitoritiOluwatijẹrisimi, Olodumaresitipọnmiloju?
22BẹniNaomisipada,atiRutuaraMoabu,ayaọmọrẹ, pẹlurẹ,tiotiilẹMoabupadawá:nwọnsiwásiBetlehemu niibẹrẹikoreọkà-barle.
ORI2
1NÁómìsìníìbátanọkọrẹkan,ọlọrọkan,látiìdílé Elimeleki;orúkærÆsìniBóásì .Onsiwifunupe,Lọ,ọmọbinrinmi.
3Onsilọ,osiwá,osipeṣẹ-ọkàninuokotọawọnolukore: osifẹmọlẹsiapakanokonatiBoasi,tiiṣeibatan Elimeleki.
4Sikiyesii,BoasisitiBetlehemuwá,osiwifunawọn olukorepe,KiOLUWAkiowàpẹlunyinNwọnsidaa lohùnpe,KiOLUWAbusiifunọ.
5NigbananiBoasiwifuniranṣẹrẹtiafiṣeoloriawọn olukorepe,Ọmọbinrintaniyi?
6Ìránṣẹtíafiṣeolóríàwọnolùkórènáàdáhùnpé, “ỌdọmọbìnrinaráMóábùtíóbáNáómìpadàlátiilẹ Móábùni.
7Osiwipe,Emibẹnyin,jẹkiemipeṣẹ,kiemisikoawọn olukorejọlãrinawọnití:bẹliosiwá,osidurolatiowurọ titiofidiisisiyi,osijokodiẹninuile
8NigbananiBoasiwifunRutupe,Iwọkògbọ,ọmọbinrin mi?Máṣelọpeṣẹ-ọkàniokomiran,bẹnikiomásilọkuro nihin;
9Jẹkiojurẹkioriokotinwọnnkórè,kiiwọkiosimatọ wọnlẹhin:emikòhatikìlọfunawọnọdọmọkunrinki nwọnkiomáṣefọwọkànọ?nígbàtíòùngbẹbáńgbẹọ,lọ síibiìkòkòkíosìmunínúèyítíàwọnọdọkùnrinnáàfa 10Nigbanaliodojubolẹ,ositẹararẹbalẹ,osiwifunu pe,Ẽṣetiemifiriore-ọfẹliojurẹ,tiiwọofimọmi, nigbatialejòliemiiṣe?
,tíosìtidéọdọàwọnènìyàntíìwọkòmọrí
12KiOLUWAkiosanafuniṣẹrẹ,atiẹkúnkikunliaofi funọlatiọdọOluwaỌlọrunIsraeliwá,labẹiyẹiyẹẹniti iwọtigbẹkẹle
13Onsiwipe,Jẹkiemiriojurereliojurẹ,oluwami; nitoritiiwọtitùmininu,atinitorieyitiiwọtisọrọore-ọfẹ funiranṣẹbinrinrẹ,biemikòtilẹdabiọkanninuawọn iranṣẹbinrinrẹ.
14Boasisiwifunupe,Niakokoonjẹiwọwá,iwọsijẹ ninuakarana,kiositúmorselrẹsinukikanÓsìjókòó lẹgbẹẹàwọnolùkórè:ósìdéọdọọkàrẹtíógbẹ,ósìjẹun, ósìtó,ósìkúrò
15Nigbatiosididelatipèṣẹ-ọkà,Boasisipaṣẹfunawọn ọdọmọkunrinrẹ,wipe,Jẹkiopeṣẹ-ọkàanilãrinití,ẹmási ṣekẹgànrẹ
16Sijẹkidiẹninuẹkúnèterẹṣubupẹlu,kiosifiwọn silẹ,kiolepèṣẹwọn,másiṣebaawi.
17Bẹliopèṣẹninuokotitiofidiaṣalẹ,osigúneyitioti pèṣẹ:ositoìwọnefaọkà-barlekan
18Osigbée,osiwọinuilulọ:iya-ọkọrẹsiriohuntiosè: osimújade,osifieyitiopamọlẹhinigbatioyó
19Iya-ọkọrẹsiwifunupe,Niboniiwọtipèṣẹlioni?ati niboniiwọṣe?Ibukúnnifunẹnitiomọọ.Osifiiya-ọkọ rẹhànẹnitiotibáṣiṣẹ,osiwipe,Boasiliorukọọkunrinna timobábáṣeloni
20Naomisiwifunayaọmọrẹpe,Alabukún-funliẹniti OLUWA,tikòfiãnurẹsilẹfunawọnalãyeatiokúNaomi
siwifunupe,Ọkunrinnasunmọwa,ọkanninuawọn ibatanwa.
21RúùtùaráMoabusìwípé,"Ówífúnmipẹlúpé,Ìwọ yóòmáagbààwẹlẹgbẹẹàwọnọdọmọkùnrinmi,títítíwọn fiparígbogboìkórèmi.
22NaomisiwifunRutuayaọmọrẹpe,Odara,ọmọbinrin mi,kiiwọkiojadepẹluawọniranṣẹbinrinrẹ,kinwọnkio mábapaderẹliokomiran.
23BẹliofiararẹṣinṣintiawọnọmọbinrinBoasi,lati pèṣẹ-ọkàtitiofideopinikoreọkà-barleatitialikama;ósì báìyáọkọrẹgbé
ORI3
1NIGBANAniNaomiiya-ọkọrẹwifunupe,Ọmọbinrin mi,emikìyiohawáibiisimifunọ,kioledarafunọ?
2NjẹnisisiyiBoasikọiṣeibatanwa,awọnwundiaẹniti iwọwà?Kiyesii,ofẹọkàbarlelialẹyiniilẹ-ipakà
3Nitorinawẹararẹ,kiosifiororoyànọ,kiosifiraiment rẹsiọ,kiosigbéọsọkalẹsiilẹ:ṣugbọnkiiwọkiomáṣe fiararẹmọfunọkunrinna,titiyiofijẹ,tiyiosimu
4Yiosiṣe,nigbatiobadubulẹ,kiiwọkiosikiyesiibiti onodubulẹsi,kiiwọkiosiwọle,kiosiṣíaṣọẹsẹrẹ,kio sidubulẹ;onosisọohuntiiwọoṣefunọ
5Onsiwifunupe,Gbogboeyitiiwọwifunmiliemioṣe.
6Osisọkalẹlọsiilẹipakà,osiṣegẹgẹbigbogboeyiti iya-ọkọrẹfiaṣẹfunu
7NigbatiBoasisijẹ,tiosimu,tiinurẹsidùn,osilọ dubulẹliopinòkitiọkà:osiwájẹjẹ,osiṣíaṣọẹsẹrẹ,osi dubulẹ
8Osiṣeliọganjọ,liẹrubaọkunrinna,osiyipada:si kiyesii,obinrinkandubulẹliẹsẹrẹ
9Onsiwipe,Taniiwọiṣe?Onsidahùnwipe,EmiRutu iranṣẹbinrinrẹni:nitorinanaaṣọigunwarẹbòiranṣẹbinrin rẹ;nitoritiojẹibatantiosunmọ
10Osiwipe,OlubukúnliiwọlatiọdọOluwawá, ọmọbinrinmi:nitoritiiwọtiṣeore-ọfẹniigbehinjùtiiṣaju lọ,niwọnbiiwọkòtitẹleawọnọmọkunrinlẹhin,ibaṣe talakàtabiọlọrọ
11Njẹnisisiyi,ọmọbinrinmi,mábẹru;Emioṣesiọ gbogboeyitiiwọbère:nitorigbogboilueniamiliomọpe, obinrinolododoniiwọiṣe
12Njẹnisisiyi,nitõtọ,liemijẹibatanrẹtiosunmọọ: ṣugbọnibatankanmbẹtiosunmọmi
13Durolialẹyi,yiosiṣeliowurọ,pebionobaṣeipín ibatanfunọ,daradara;jẹkioṣeiṣeibatan:ṣugbọnbionkò baṣeiṣeibatansiọ,nigbanaliemioṣeiṣeibatansiọ,bi OLUWAtiwà:dubulẹtitidiowurọ.
14Osidubulẹliẹsẹrẹtitiofidiowurọ:osididekiẹnikan kiotomọẹlomiranOnsiwipe,Kiamáṣemọpeobinrin kanwásiilẹipakà
15Osiwipe,Múaṣọ-ikeletiiwọnilararẹwá,kiosidìi múNigbatiosidìi,owọnòṣuwọnọkàbarlemẹfa,osifi léelori:osilọsinuilu
16Nigbatiosideọdọiya-ọkọrẹ,owipe,Taniiwọ, ọmọbinrinmi?Ósìsọgbogboohuntíọkùnrinnáàṣesíi fúnun.
17Onsiwipe,Oṣuwọnọkàbarlemẹfawọnyiliofifunmi; nitoritiowifunmipe,Máṣelọofosọdọiya-ọkọrẹ 18Nigbanaliowipe,jokojẹ,ọmọbinrinmi,titiiwọofi mọbiọrannayiotiri:nitoritiọkunrinnakiyiowàniisimi, titiyiofiparinkannalioni
1NIGBANAniBoasigòkelọsiẹnu-ọna,osijokonibẹ:si kiyesii,ibatanẹnitiBoasisọrọrẹmbọ;funẹnitiowipe, Háà,irúeyi!yipadasiapakan,jokonihin.Osiyàsiapakan, osijoko
2Osimúọkunrinmẹwaninuawọnàgbailuna,osiwipe, Ẹjokonihin.Nwọnsijoko.
3Ósọfúnìbátannáàpé,“Naomi,tíótiilẹMoabupadawá, tailẹkantíójẹtiElimelekiarakunrinwa
4Emisiròlatipolongoọ,wipe,Raaniwajuawọnolugbe, atiniwajuawọnàgbaeniamiBiiwọbaràapada,ràa pada:ṣugbọnbiiwọkòbaràa,njẹsọfunmi,kiemikiole mọ:nitorikòsiẹnikanlatiràapadalẹhinrẹ;emisiwa lẹhinrẹOnsiwipe,Emioràapada
5NígbànáàniBóásìwípé,“Níọjọtíìwọbárailẹnáà lọwọNáómì,ìwọyóòsìràálọwọRúùtùaráMóábù,aya ẹnitíókú,látigbéorúkọòkúdìdelóríogúnrẹ
6Arakunrinnasiwipe,Emikòleràapadafunarami,ki emikiomábabailẹ-inímijẹ:iwọràẹtọmisiararẹ; nítoríèmikòlèràápadà
7NísisìyíèyíniọnàìgbààtijọníÍsírẹlìnípaìràpadààtiní tiìyípadà,látifiìdíohungbogbomúlẹ;ọkunrinkanbọ bàtarẹ,osififunọmọnikejirẹ:eyisiliẹríniIsraeli 8NitorinaibatannawifunBoasipe,Raafunọ.Nítorínáà, óbọbàtàrẹkúrò
9Boasisiwifunawọnàgbagba,atifungbogboawọnenia pe,Ẹnyinliẹlẹrilioni,pemotiràgbogbonkantiiṣeti Elimeleki,atigbogboeyitiiṣetiKilioniatitiMaloni,lọwọ
Naomi
10PẹlupẹluRutuaraMoabu,ayaMaloni,liemitiràlatiṣe ayami,latigbéorukọokúdideloriilẹ-inírẹ,kiamábake orukọokúkurolãrinawọnarakunrinrẹ,atiliẹnu-bodeti ipòrẹ:ẹnyinliẹlẹrilioni.
11Gbogboawọneniatiowàliẹnu-bode,atiawọnàgba, wipe,AwaliẹlẹriKíOLUWAṣeobinrintíówọinúilérẹ bíRakẹliatiLea,tíàwọnmejeejikọiléIsraẹli; 12KiilerẹkiosidabiileFaresi,tiTamaribifunJuda, ninuirú-ọmọtiOLUWAyiofifunọlatiinuọmọbinrinyi wá.
13BoasisifẹRutu,onsiṣeayarẹ:nigbatiosiwọletọọlọ, OLUWAsifunulioyun,osibíọmọkunrinkan
14.AwọnobinrinsiwifunNaomipe,OlubukúnliOluwa, tikòfiọsilẹlialainiibatanlioni,kiorukọrẹkioledi olokikiniIsraeli
15Onosijẹolutunṣeigbesi-ayerẹ,atiolutọjuọjọ-oritio fẹlẹfẹlẹ:nitoriọmọbinrinrẹninuofin,tiofẹranrẹ,eyitio darafunọjuọmọkunrinmejelọ,tiotibii.
16Naomisimúọmọna,ositẹẹsiaiyarẹ,osidiolutọju rẹ
17Awọnobinrinaladugborẹsisọọliorukọ,wipe,Abi ọmọkunrinkanfunNaomi;nwọnsisọorukọrẹniObedi: onnibabaJesse,babaDafidi
18WọnyisiniiranFaresi:FaresisibiHesroni; 19HesronisibiRamu,atiRamusibiAminadabu; 20AminadabusibiNaṣoni,atiNaṣonisibiSalmoni; 21SalmonisibiBoasi,BoasisibiObedi; 22ObedisibiJesse,JessesibiDafidi